Onídájọ́ 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sísérà sọ fún Jáélì pé, “Kí ó dúró lẹ́nu ọ̀nà àgọ́, àti pé bí ẹnikẹ́ni bá béèrè bóyá òun wà níbẹ̀ kí ó sọ pé, ‘Kò sí ẹnìkankan ní ibẹ̀.’ ”

Onídájọ́ 4

Onídájọ́ 4:16-22