Onídájọ́ 4:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sísérà wí pé, “Òrùngbẹ ń gbẹ́ mí, jọ̀wọ́ fún mi ní omi mu.” Ó sì sí awọ wàrà kan, ó sì fún-un mu ó sì tún daṣọ bò ó padà.

Onídájọ́ 4

Onídájọ́ 4:14-22