Onídájọ́ 21:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, kò sí ọba ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì; olúkúlùkù sì ń ṣe bí ó ti tọ́ ní ojú ara rẹ̀.

Onídájọ́ 21

Onídájọ́ 21:24-25