Onídájọ́ 21:24-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Ní àkókò náa, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ibẹ̀, wọ́n lọ sí ilé àti ẹ̀yà rẹ̀ olúkúlùkù sí ilẹ̀ ìní rẹ̀.

25. Ní àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, kò sí ọba ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì; olúkúlùkù sì ń ṣe bí ó ti tọ́ ní ojú ara rẹ̀.

Onídájọ́ 21