Onídájọ́ 15:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi iná ran àwọn ètúfù tí ó so náà, ó sì jọ̀wọ́ wọn lọ́wọ́ lọ sínú àwọn oko ọkà àwọn Fílístínì. Ó jó àwọn pòpóòrò ọkà tí ó dúró àti àwọn tí a dì ní ìtí, ìtí, pẹ̀lú àwọn oko àjàrà àti ólífì.

Onídájọ́ 15

Onídájọ́ 15:2-7