Onídájọ́ 15:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì jáde lọ, ó mú ọ̀ọ́dúnrún (300) kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ ó so ìrù wọn mọ́ ara wọn ní méjìméjì. Ó mú ètùfù iná, ó so ó mọ́ àwọn ìrù tí ó so pọ̀.

Onídájọ́ 15

Onídájọ́ 15:2-9