Onídájọ́ 11:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ọ̀ọ́dúnrún ọdún (300) ni Ísírẹ́lì fi ṣe àtìpó ní Hésíbónì, Áróérì àti àwọn ìgbéríko àti àwọn ìlú tí ó yí Ánónì ká. Èéṣe tí ìwọ kò fi gbà wọ́n padà ní àsìkò náà?

Onídájọ́ 11

Onídájọ́ 11:22-33