Ọbadáyà 1:20-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Àwọn ìgbèkùn Ísírẹ́lì tí ó wà níKénánì yóò ni ilẹ̀ títí dé Séréfátì;àwọn ìgbékùn láti Jérúsálẹ́mùtí ó wà ní Séfárádìyóò ni àwọn ìlú Gúsù ní ìní

21. Àwọn olùgbàlà yóò sì gòkè Síónì wáláti jọba lé orí àwọn òkè Ísọ̀.Ìjọba náà yóò sì jẹ́ ti Olúwa.

Ọbadáyà 1