Ọbadáyà 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olùgbàlà yóò sì gòkè Síónì wáláti jọba lé orí àwọn òkè Ísọ̀.Ìjọba náà yóò sì jẹ́ ti Olúwa.

Ọbadáyà 1

Ọbadáyà 1:20-21