Nọ́ḿbà 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbà mìíràn ìkúùkù lè wà lórí àgọ́ fún ọjọ́ díẹ̀; ṣíbẹ̀ ní àṣẹ Olúwa, wọn yóò dúró ní ibùdó, bí ó sì tún yá, ní àṣẹ rẹ̀ náà ni wọn yóò gbéra.

Nọ́ḿbà 9

Nọ́ḿbà 9:17-21