Nọ́ḿbà 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní orí pẹpẹ wúrà ni kí wọn ó tẹ́ aṣọ aláró kan sí, wọn yóò sì fi bò ó, kí wọ́n sì fi òpó rẹ̀ bọ ààyè rẹ̀.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:8-12