Nọ́ḿbà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí wọn ó fi awọ ẹran yí fìtílà àti gbogbo ohun èlò rẹ, kí wọn kí ó sì gbé e lé orí férémù tí wọn yóò fi gbé e.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:4-16