Nọ́ḿbà 3:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iye gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, èyí tí wọ́n kà jẹ́ igba mọ́kànlélọ́gbọ̀n (6,200).

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:32-40