Nọ́ḿbà 3:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élíásárì ọmọ Árónì àlùfáà ni alákóso gbogbo àwọn olórí ìdílé Léfì. Òun ni wọ́n yàn lórí gbogbo àwọn tí yóò máa tọ́jú ibi mímọ́.

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:26-41