Nọ́ḿbà 3:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ni yóò máa tọ́jú àpótí ẹ̀rí, tabílì, ọ̀pá fìtílà, àwọn pẹpẹ, gbogbo ohun èlò ibi mímọ́ tí à ń lò fún iṣẹ́ ìsìn, aṣọ títa àti gbogbo ohun tó jẹ mọ́ lílò wọn.

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:23-37