Nọ́ḿbà 29:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Pẹ̀lú ẹ̀jẹ́ yín, àti ẹbọ àtinúwá yín, kí ẹ̀yin kí o pèsè fún Olúwa ní àjọ yín, ẹbọ sísun, ẹbọ ohun jíjẹ, ẹbọ ohun mímu àti ẹbọ ìkẹ́gbẹ́ yín.’ ”

Nọ́ḿbà 29

Nọ́ḿbà 29:36-40