Nọ́ḿbà 29:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ pẹ̀lú ẹbọ sísun gbogbo ìgbà àti ẹbọ ohun jíjẹ àti ẹbọ ohun mímu.

Nọ́ḿbà 29

Nọ́ḿbà 29:28-40