Nọ́ḿbà 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún aláìmọ́ ènìyàn, mú eérú díẹ̀ lára eérú ọrẹ ìwẹ̀nùmọ́ sínú ìgò, kí o sì da omi tó ń sàn lée lórí.

Nọ́ḿbà 19

Nọ́ḿbà 19:10-22