Nọ́ḿbà 19:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹnikẹ́ni tí ó bá wà ní ìta tí ó sì fi ọwọ́ kan ẹni tí a fi idà pa tàbí ẹni tí ó kú ikú àtọ̀runwá, tàbí bí ẹ̀nìkan bá fi ọwọ́ kan egungun òkú ènìyàn tàbí iṣà òkú, yóò jẹ́ aláìmọ́ fún ọjọ́ méje.

Nọ́ḿbà 19

Nọ́ḿbà 19:6-20