Mátíù 27:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti wákàtí kẹfà ni òkùnkùn fi sú bo gbogbo ilẹ̀ títí dé wákàtí kẹsàn-án ọjọ́

Mátíù 27

Mátíù 27:35-54