Mátíù 27:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà, àwọn olè tí a kàn mọ́ àgbélébùú pẹ̀lú Rẹ̀ fi í ṣe ẹlẹ́yà.

Mátíù 27

Mátíù 27:36-47