Mátíù 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

È é ha ti ṣe, obìnrin yìí ìbá tà á ní owó púpọ̀, kí a sì fi owó náà fún àwọn aláìní.”

Mátíù 26

Mátíù 26:1-12