Mátíù 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù ti mọ èrò ọkàn wọn, ó wí pé, “È é ṣe ti ẹ̀yin fi ń dá obìnrin yìí lẹ́bi? Ó ṣe ohun tí ó dára fún mi

Mátíù 26

Mátíù 26:7-20