Mátíù 26:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbànújẹ́ sì bo ọkàn wọn nígbà tí wọ́n gbọ́ èyí. Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí i bi í pé, “Olúwa, èmi ni bí?”

Mátíù 26

Mátíù 26:20-32