Mátíù 26:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà tí wọ́n sì ń jẹun, ó wí pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀kan nínú yín yóò fi mí hàn.”

Mátíù 26

Mátíù 26:18-28