Mátíù 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègbé ni fún ayé nítorí gbogbo ohun ìkọ̀sẹ̀ rẹ̀! Ohun ìkọ̀sẹ̀ kò le ṣe kó má wà, ṣùgbọ́n ègbé ni fún ọkùnrin náà nípaṣẹ̀ ẹni tí ìkọ̀sẹ̀ náà ti wá!

Mátíù 18

Mátíù 18:5-15