Mátíù 15:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù ti ibẹ̀ lọ sí òkun Gálílì. Ó gun orí òkè, o sì jókòó níbẹ̀.

Mátíù 15

Mátíù 15:24-39