Mátíù 15:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì sọ fún obìnrin náà pé, “Ìgbàgbọ́ ńlá ni tìrẹ! A sì ti dáhùn ìbéèrè rẹ.” A sì mú ọmọbìnrin rẹ̀ lára dá ní wákàtí kan náà.

Mátíù 15

Mátíù 15:26-35