Mátíù 13:57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú bí wọn sí i.Ṣùgbọ́n Jésù wí fún wọn pé, “Wòlíì a máa lọ́lá ní ibòmíràn, àfi ní ilé ara rẹ̀ àti ní ìlú ara rẹ̀ nìkan ni wòlíì kò ti lọ́lá.”

Mátíù 13

Mátíù 13:55-58