Mátíù 13:56 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn arábìnrin rẹ̀ gbogbo ha kọ́ ni ó ń bá wa gbé níhìn-ín yìí, nígbà náà níbo ni ọkùnrin yìí ti rí àwọn nǹkan wọ̀nyí?”

Mátíù 13

Mátíù 13:46-58