Málákì 1:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀: ọ̀rọ̀ Olúwa sí Ísírẹ́lì láti ẹnu Málákì.

2. “Èmí ti fẹ́ ẹ yín,” ni Olúwa wí.“Ṣùgbọ́n ẹ̀yín béèrè pé, ‘Báwo ni ìwọ ṣe fẹ́ wa?’“Ísọ̀ kì í ha ṣe arákùnrin Jákọ́bù bí?” ni Olúwa wí. “Ṣíbẹ̀ èmi fẹ́ràn Jákọ́bù,

3. ṣùgbọ́n Ísọ̀ ni èmi kórìíra, mo ti sọ àwọn òkè-ńlá rẹ̀ di aṣálẹ̀, mo sì fi ìní rẹ̀ fún àwọn akáta ihà.”

Málákì 1