Málákì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmí ti fẹ́ ẹ yín,” ni Olúwa wí.“Ṣùgbọ́n ẹ̀yín béèrè pé, ‘Báwo ni ìwọ ṣe fẹ́ wa?’“Ísọ̀ kì í ha ṣe arákùnrin Jákọ́bù bí?” ni Olúwa wí. “Ṣíbẹ̀ èmi fẹ́ràn Jákọ́bù,

Málákì 1

Málákì 1:1-3