Máàkù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ yẹra kúrò níbẹ̀ lọ sí etí òkun. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn láti Gálílì àti Jùdíà sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Máàkù 3

Máàkù 3:5-16