Máàkù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójúkan-náà, àwọn Farisí jáde lọ, láti bá àwọn ọmọ ẹ̀yin Hẹ́rọ́dù gbìmọ̀ pọ̀, bí wọn yóò ṣe pa Jésù.

Máàkù 3

Máàkù 3:1-10