Máàkù 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù rántí pé Jésù ti bá igi náà wí. Nígbà náà ni ó sọ fún Jésù pé, “Rábì, Wò ó! Igi ọ̀pọ̀tọ́ tí ìwọ fi bú ti gbẹ!”

Máàkù 11

Máàkù 11:20-31