Máàkù 11:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, bí wọ́n ti ń kọjá lọ, wọ́n rí igi ọ̀pọ̀tọ́ tí Jésù fi bú. Wọ́n rí i pé ó ti gbẹ tigbòǹgbò-tigbòǹgbò.

Máàkù 11

Máàkù 11:19-25