Máàkù 10:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣùgbọ́n láti jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ní ọwọ́ ọ̀sì mi kì ì ṣe ti èmi láti fi fún ni: bí kò ṣe fún àwọn ẹni tí a ti pèṣè rẹ̀ sílẹ̀ fún.”

Máàkù 10

Máàkù 10:38-46