Máàkù 10:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn méjèèjì dáhùn pé, “Àwa pẹ̀lú lè ṣe bẹ́ẹ̀.” Jésù wí fún wọn pé, “Lóòótọ́ ni ẹ̀yin ó mu ago ti èmi yóò mu, àti bamitíìsímù tí a sí bamitíìsì mi ni a ó fi bamitíìsì yín,

Máàkù 10

Máàkù 10:37-46