Lúùkù 16:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì wí fún yín, ẹ fi mámónì àìṣòótọ́ yan ọ̀rẹ́ fún ara yín pé, nígbà tí yóò bá yẹ, kí wọn kí ó le gbà yín sí ibùjókòó wọn títí ayé.

Lúùkù 16

Lúùkù 16:5-12