Lúùkù 16:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa rẹ̀ sì yin aláìṣòótọ́ ìríjú náà, nítorí tí ó fi ọgbọ́n ṣe é: àwọn ọmọ ayé yìí sáà gbọ́n ní Ìran wọn ju àwọn ọmọ ìmọ́lẹ̀ lọ.

Lúùkù 16

Lúùkù 16:7-11