Jóṣúà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Jẹ́ alágbára, kí o sì mú àyà le gidigidi. Kí o sì sọ́ra láti pa gbogbo òfin tí Móṣè ìránṣẹ́ mi fún ọ mọ́, Má ṣe yà kúrò nínú u rẹ̀ sí ọ̀tún tàbí sí òsì, kí ìwọ kí ó lè ṣe rere níbikíbi tí ìwọ bá ń lọ.