Jóòbù 39:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò ní àánú sí àwọn ọmọ rẹ̀ bíẹni pé wọn kì í ṣe tirẹ̀; asán ni iṣẹ́ rẹ̀, láì ní ìbẹ̀rù;

Jóòbù 39

Jóòbù 39:6-26