Jóòbù 39:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó sì gbàgbé pé, ẹ̀sẹ̀ lè tẹ̀ wọ́nfọ́, tàbí pé ẹranko ìgbẹ́ lè tẹ̀ wọ́n fọ́.

Jóòbù 39

Jóòbù 39:5-18