Jóòbù 39:13-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. “Ìyẹ́ abo ògòǹgò ń fi ayọ̀ fì;Ṣùgbọ́n a kò le fi àká we ara wọn ní ìyẹ́ àti ìhùhù

14. Ó yé ẹ̀yìn rẹ̀ sílẹ̀ lórí ilẹ̀,a sì mú wọn gbóná nínú ekuru;

15. Tí ó sì gbàgbé pé, ẹ̀sẹ̀ lè tẹ̀ wọ́nfọ́, tàbí pé ẹranko ìgbẹ́ lè tẹ̀ wọ́n fọ́.

Jóòbù 39