Jóòbù 26:10-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Ó fi idẹ yí omi òkun ká, títí déààlà ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn.

11. Ọ̀wọ̀n òpó ọ̀run wárìrì, ẹnu sì yàwọ́n sì ìbàwí rẹ̀.

12. Ó fi ipá rẹ̀ dààmú omi òkun; nípaòye rẹ̀, ó gé Ráhábù sí wẹ́ẹ́wẹ́.

13. Nípa ẹ̀mí rẹ̀ ni ó ti ṣe ọ̀run níọ̀sọ́; ọwọ́ rẹ̀ ni ó ti dá ejò wíwo nì.

Jóòbù 26