Jóòbù 26:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ẹ̀mí rẹ̀ ni ó ti ṣe ọ̀run níọ̀sọ́; ọwọ́ rẹ̀ ni ó ti dá ejò wíwo nì.

Jóòbù 26

Jóòbù 26:10-14