Jóòbù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún di ọjọ́ kan nígbà tí àwọn ọmọ Ọlọ́run wá síwájú Olúwa, Sàtánì sì wá pẹ̀lú wọn láti pe níwájú Olúwa.

Jóòbù 2

Jóòbù 2:1-3