Jóòbù 16:1-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ní Jóòbù dáhùn, ó sì wí pé:

2. “Èmi ti gbọ́ irú ohun pípọ̀ bẹ́ẹ̀ ríayọnilẹ́nu onítùnú ènìyàn ní gbogbo yín.

3. Ọ̀rọ̀ asán lè ni òpin? Tàbí nín ni ógbó ọ láyà tí ìwọ fi dáhùn?

4. Èmi pẹ̀lú le sọ bí ẹ̀yin; bí ọkànyín bá wà ní ipò ọkàn mi, èmile íkọ ọ̀rọ̀ pọ̀ si yin ni ọ̀run, èmi a sì mi orí mi sí i yín.

5. Èmi ìbá fi ọ̀rọ̀ ẹnu mi gbà yín niìyànjú, àti ṣíṣí ètè mi ìbá sì tu ìbìnújẹ́ yín.

6. “Bí èmi tilẹ̀ sọ̀rọ̀, ìbìnújẹ́ mi kò tù;bí mo sì tilẹ̀ dákẹ́, níbo ni ìtùnú mí dé?

Jóòbù 16