Jóòbù 16:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ìbá fi ọ̀rọ̀ ẹnu mi gbà yín niìyànjú, àti ṣíṣí ètè mi ìbá sì tu ìbìnújẹ́ yín.

Jóòbù 16

Jóòbù 16:1-13