Jónà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ṣọ̀kalẹ̀ lọ sí ìṣàlẹ̀ àwọn òkè ńlá;ilẹ̀ ayé pẹ̀lú ìdènà rẹ̀ yí mi ká títí:ṣùgbọ́n ìwọ ti mú ẹ̀mí mi wá sókè láti inú ibú wá, Olúwa Ọlọ́run mi.

Jónà 2

Jónà 2:1-7